Aller au contenu principal

Joseph Stalin


Joseph Stalin


Joseph Stalin (orúko àbísọ Ioseb Besarionis dze Jughashvili ní èdè Georgia tàbí Iosif Vissarionovich Dzhugashvili ní orúko bàbá ní Russia; 18 December 1878 – 5 March 1953) lo jẹ́ Akòwé Àgbà Ẹgbẹ́ Kọ́mmústí tí Ìsòkan Sofieti fún Ìgbìmò Gbàngbà láti 1922 títí de ọjọ́ ikú re ní 1953. Léyìn ikú Lenin ní 1924, o di olórí orílẹ̀-èdè Ìsòkan Sofieti.


Ìtókasí


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Joseph Stalin by Wikipedia (Historical)