Aller au contenu principal

Deng Xiaoping


Deng Xiaoping


Orúkọ ará Ṣáínà kan nìyí; orúkọ ìdílé ni Deng.

Deng Xiaoping (pípè: [tə̂ŋ ɕjɑ̀ʊ̯pʰǐŋ] ( gbígbọ́); 22 August 1904  – 19 February 1997) je oloselu, babaalu, aserojinle ati diplomati ara Saina. Gege bi asiwaju Egbe Komunisti ile Saina, Deng je alatunda to siwaju Saina lati sunmo okowo oja. Botilejepe Deng ko ni aga gege bi olori orile-ede, olori ijoba tabi Akowe Agba Egbe Komunisti ile Saina (to je ipo gigajulo ni Saina Onikomunisti), sibesibe o sise bi asiwaju pataki Orileolominira awon Ara saina lati 1978 titi de 1992.


Itokasi


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Deng Xiaoping by Wikipedia (Historical)



INVESTIGATION