Aller au contenu principal

Dígí


Dígí


Dígí tàbí Díngí ìwògbè ni ohun èlò kan tí a ń lò láti fi wo àwòrán ara ẹni tí yóò sì gbé àwòrán náà wá fúni gẹ́gẹ́ a ti rí.

Oríṣi dígí tí ó wà

Lára àwọn dígí tí ó wọ́pọ̀ tí a má ń rí tàbí lò jùlọ ni panragandan (plain mirror). Èkejì ni dígí ẹlẹ́bùú (cirved mirror), wọ́n ma ń lo dígí yìí láti fi pèsè irúfẹ́ àwọn dígí mìíràn tí a lè fi wo ohun tó bá wẹ́ níye.

Ìwúlò dígí

  1. A ma ńblo dígí fún oríṣríṣi nkan. Lára rẹ̀ ni kí á fi wo ara ẹni yálà ojú tàbí ibi kọ́lọ́fín tí ojú kò lè ká lára. Ìdí nìyí tí Yorùbá fi ma ń pèé ní ìwògbè.
  2. Wọ́n ms ń lo dígí fún wíwo ẹ̀yìn lára ọkọ̀, kẹẹ̀kẹ́ ológere, Kẹ̀kẹ́ Alùpùpù àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.
  3. Wọ́n ma ń lòó láti fi ṣẹ̀ṣọ́ ara Ilé.
  4. Àwọn Dókítà olùtọ́jú eyín náà ma ń lòó láti fi wo kọ̀rọ̀ ẹnu
  5. Wọ́n ń lo dígí láti fi pèsè ìléjú ẹ̀rọ ayàwòrán àti bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ lọ.

Àwọn Ìtọ́ka sí


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Dígí by Wikipedia (Historical)