Aller au contenu principal

Ipinle Kano


Ipinle Kano


Ìpínlẹ̀ Kánò jẹ́ olú ìlú Ìpínlẹ̀ Kánò àti ìlú tí ó tóbijùlo ẹ̀kẹta ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà lẹ́yìn ìlú Ìbàdàn àti ìlú Èkó. Gẹ́gẹ́ bí ìkànìyàn ọdún 2006, Kano jẹ́ ìpínlẹ̀ tí ó ní èrò jùlọ ní orílẹ̀̀ èdè Nàìjíríà. Àwọn ibi tó lajú níbẹ̀ gba ìlẹ̀ tó tóbi tó 137 km2 tí ó sì ní àwọn ìjọba ìbílẹ̀ mẹ́fà — Kano Municipal, Fagge, Dala, Gwale, Tarauni àti Nasarawa — pẹ̀lú olùgbélú 2,163,225 ní ìkànìyàn ọdún 2006.

Oro Adayeba ni Ipinle Kano

  1. Gassiterite
  2. Idẹ
  3. Gemstone
  4. Glass-sand
  5. Sinkii
  6. Pyrochinre & Tantalite

Ẹkọ

Ile-iwe giga

Ìwé àkàsíwájú

  • Maconachie, Roy (2007). Urban Growth and Land Degradation in Developing Cities: Change and Challenges in Kano, Nigeria. King's SOAS Studies in Development Geography. Ashgate Publishing. ISBN 978-0-7546-4828-4. 
  • Barau, Aliyu Salisu (2007). The Great Attractions of Kano. Research and Documentation publications. Research and Documentation Directorate, Government House Kano. ISBN 978-8109-33-0. 



Itokasi


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Ipinle Kano by Wikipedia (Historical)