Microsoft jẹ́ ilé-iṣẹ́ ọ̀nà-ìmúṣẹ kọ̀m̀pútà onileabinibi pupo to n sedagbasoke, seko, segbalaye ati salafeyinti orosirisi awon eso atosiro komputa fun awon ero onisiro. Oluile-ise wa ni Redmond ni Ipinle Washington ni ile Amerika, eso re to lere julo ni Microsoft Windows to je sistemu afisise ati Microsoft Office to je imulo fun komputa.
Microsoft Video 1 ni ona igekurupapo faili fun lilo ninu Komputa.
Microsoft Windows je awon atosiro sistemu isise fun awon komputa ti ile-ise Microsoft n se.
Windows Vista je sistemu isise komputa ti Microsoft se fun awon komputa adani.
Owlapps.net - since 2012 - Les chouettes applications du hibou