![Ishaya Aboi Shekari Ishaya Aboi Shekari](/modules/owlapps_apps/img/nopic.jpg)
Ishaya Aboi Shekari jẹ́ ọmọ orílẹ-èdè Naijiria àti gómìnà ológun ní Ìpínlẹ̀ Kano tẹ́lẹ̀. O wa lori ipo gomina yii lati osu kesan odun 1978 titi di osu kewa odun 1979. O tun di ipo Minisita fun ise akanse ni akoko isejoba Ogagun Babangida.
Owlapps.net - since 2012 - Les chouettes applications du hibou