Aller au contenu principal

Rabiu Kwankwaso


Rabiu Kwankwaso


Rabi'u Musa Kwankwaso FNSE (tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹẹ̀jilelogun oṣù kewa ọdún 1956) jẹ́ gbajúgbajà olóṣèlú ọmọ bíbí ìpínlẹ̀ Kano lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Òun ni gomina Ipinle Kano tele ri.

Ni odún 2022,ni won yan Rabiu Kwankwaso gege bi oludije fun aare orílẹ̀ èdè Naijiria ti odun 2023 lábẹ́ àsíyá ẹgbẹ́ òṣèlú New Nigeria People's Party.

Àwọn Ìtọ́kasí


Text submitted to CC-BY-SA license. Source: Rabiu Kwankwaso by Wikipedia (Historical)



ghbass